Diutaronomi 31:11 BIBELI MIMỌ (BM)

nígbà tí gbogbo àwọn ọmọ Israẹli bá wá sin OLUWA ní ibi tí ó yàn pé kí wọ́n ti máa sin òun, o gbọdọ̀ máa ka òfin yìí sí etígbọ̀ọ́ gbogbo wọn.

Diutaronomi 31

Diutaronomi 31:9-21