Diutaronomi 30:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Bẹ́ẹ̀ ni kò sí ní òdìkejì òkun tí ẹ óo fi wí pé, ‘Ta ni yóo la òkun kọjá fún wa, tí yóo lọ bá wa mú un wá kí á lè gbọ́ kí á sì pa á mọ́?’

Diutaronomi 30

Diutaronomi 30:9-20