Diutaronomi 30:10 BIBELI MIMỌ (BM)

bí ẹ bá gbọ́ ti OLUWA Ọlọrun yín, tí ẹ pa àwọn òfin ati ìlànà rẹ̀ mọ́ bí a ti kọ ọ́ sinu ìwé òfin yìí, tí ẹ bá sì yipada tọkàntọkàn.

Diutaronomi 30

Diutaronomi 30:4-12