Diutaronomi 3:6 BIBELI MIMỌ (BM)

A run gbogbo wọn patapata gẹ́gẹ́ bí a ti ṣe sí Sihoni, ọba Heṣiboni, tí a run gbogbo àwọn ìlú rẹ̀, ati ọkunrin, ati obinrin, ati ọmọde.

Diutaronomi 3

Diutaronomi 3:4-8