Diutaronomi 3:28 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn pàṣẹ fún Joṣua, mú un lọ́kàn le, kí o sì kì í láyà; nítorí pé, òun ni yóo ṣiwaju àwọn eniyan wọnyi lọ, tí wọn yóo fi gba ilẹ̀ tí o óo rí.’

Diutaronomi 3

Diutaronomi 3:24-29