Diutaronomi 3:17 BIBELI MIMỌ (BM)

ati ilẹ̀ Araba títí kan odò Jọdani. Láti Kinereti títí dé Òkun Araba tí wọn ń pè ní Òkun Iyọ̀, ní ẹsẹ̀ òkè Pisiga ní apá ìlà oòrùn.

Diutaronomi 3

Diutaronomi 3:8-18