Diutaronomi 3:1 BIBELI MIMỌ (BM)

“Lẹ́yìn náà, a gbéra, a doríkọ ọ̀nà Baṣani. Ogu, ọba Baṣani, ati àwọn eniyan rẹ̀ bá ṣígun wá pàdé wa ní Edirei.

Diutaronomi 3

Diutaronomi 3:1-8