Diutaronomi 29:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ẹ dé ibí yìí, Sihoni, ọba Heṣiboni ati Ogu, ọba Baṣani gbógun tì wá, ṣugbọn a ṣẹgun wọn.

Diutaronomi 29

Diutaronomi 29:3-13