Diutaronomi 29:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn títí di òní yìí, OLUWA kò tíì jẹ́ kí òye ye yín, ojú yín kò ríran, bẹ́ẹ̀ ni etí yín kò gbọ́ràn.

Diutaronomi 29

Diutaronomi 29:1-5