Diutaronomi 29:27 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìdí nìyí tí inú fi bí OLUWA sí ilẹ̀ yìí, tí ó sì mú gbogbo ègún tí a kọ sinu ìwé yìí ṣẹ lé wọn lórí.

Diutaronomi 29

Diutaronomi 29:21-29