Diutaronomi 29:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn eniyan yóo sì máa dáhùn pé, ‘Nítorí pé wọn kò mú majẹmu OLUWA Ọlọrun ṣẹ, tí ó bá àwọn baba wọn dá nígbà tí ó kó wọn jáde ní ilẹ̀ Ijipti.

Diutaronomi 29

Diutaronomi 29:19-29