Diutaronomi 28:8 BIBELI MIMỌ (BM)

“OLUWA yóo bukun ìkórè inú àká rẹ, ati gbogbo nǹkan tí o bá dáwọ́ lé. OLUWA Ọlọrun rẹ yóo bukun ọ ní ilẹ̀ tí ó fún ọ.

Diutaronomi 28

Diutaronomi 28:1-14