Diutaronomi 28:47 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí pé bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé Ọlọrun bukun yín, ẹ kọ̀, ẹ kò sìn ín pẹlu ayọ̀ ati inú dídùn.

Diutaronomi 28

Diutaronomi 28:46-51