Diutaronomi 28:43 BIBELI MIMỌ (BM)

“Àwọn àlejò tí wọ́n wà láàrin yín yóo máa níláárí jù yín lọ, ọwọ́ wọn yóo máa ròkè, ṣugbọn ní tiyín, ẹ óo di ẹni ilẹ̀ patapata.

Diutaronomi 28

Diutaronomi 28:37-47