Diutaronomi 28:41 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ óo bí ọpọlọpọ ọmọkunrin ati ọmọbinrin, ṣugbọn wọn kò ní jẹ́ tiyín, nítorí gbogbo wọn ni wọn óo kó lẹ́rú lọ.

Diutaronomi 28

Diutaronomi 28:40-44