Diutaronomi 28:4 BIBELI MIMỌ (BM)

“Yóo bukun àwọn ọmọ rẹ, ati èso ilẹ̀ rẹ, ati àwọn ẹran ọ̀sìn rẹ, ati àwọn ọmọ mààlúù rẹ, ati àwọn ọmọ aguntan rẹ.

Diutaronomi 28

Diutaronomi 28:1-13