Diutaronomi 28:37 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ óo di ẹni ìríra, ẹni àmúpòwe ati ẹni ẹ̀sín, láàrin gbogbo àwọn eniyan, níbi tí OLUWA yóo le yín lọ.

Diutaronomi 28

Diutaronomi 28:31-47