Diutaronomi 28:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Òkú rẹ yóo di ìjẹ fún àwọn ẹyẹ ati àwọn ẹranko tí ń káàkiri orí ilẹ̀ ayé, kò sì ní sí ẹnikẹ́ni tí óo lé wọn kúrò.

Diutaronomi 28

Diutaronomi 28:18-30