Diutaronomi 28:21 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA yóo rán àjàkálẹ̀ àrùn sí ọ títí tí yóo fi pa ọ́ run patapata, lórí ilẹ̀ tí ò ń wọ̀ lọ láti gbà.

Diutaronomi 28

Diutaronomi 28:15-28