Diutaronomi 27:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Òkúta tí wọn kò gbẹ́ ni kí ẹ fi kọ́ pẹpẹ kan fún OLUWA Ọlọrun yín kí ẹ sì rú ẹbọ sísun sí i lórí rẹ̀.

Diutaronomi 27

Diutaronomi 27:1-16