Diutaronomi 27:25 BIBELI MIMỌ (BM)

“ ‘Ẹni ìfibú ni ẹnikẹ́ni tí ó bá gba àbẹ̀tẹ́lẹ̀ láti pa aláìṣẹ̀.’“Gbogbo eniyan yóo sì dáhùn pé, ‘Amin.’

Diutaronomi 27

Diutaronomi 27:18-26