Diutaronomi 27:16 BIBELI MIMỌ (BM)

“ ‘Ẹni ìfibú ni ẹnikẹ́ni tí ó bá tàbùkù baba tabi ìyá rẹ̀.’“Gbogbo eniyan yóo sì dáhùn pé, ‘Amin.’

Diutaronomi 27

Diutaronomi 27:15-20