Diutaronomi 27:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Mose, pẹlu gbogbo àwọn àgbààgbà Israẹli, sọ fún àwọn eniyan náà pé, “Ẹ máa pa gbogbo òfin tí mo fun yín lónìí mọ́.

Diutaronomi 27

Diutaronomi 27:1-8