Diutaronomi 26:16 BIBELI MIMỌ (BM)

“OLUWA Ọlọrun rẹ pàṣẹ fún ọ lónìí, pé kí o máa pa gbogbo ìlànà ati òfin wọnyi mọ́. Nítorí náà, máa pa gbogbo wọn mọ́ tọkàntọkàn.

Diutaronomi 26

Diutaronomi 26:11-19