Diutaronomi 26:11 BIBELI MIMỌ (BM)

kí o sì bẹ̀rẹ̀ sí yọ̀ fún ohun tí OLUWA fún ìwọ ati ìdílé rẹ, kí àwọn ọmọ Lefi ati àwọn àlejò tí ń gbé ààrin yín náà sì máa bá ọ ṣe àjọyọ̀.

Diutaronomi 26

Diutaronomi 26:6-13