Diutaronomi 25:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọn yóo ka ọmọkunrin kinni tí opó yìí bá bí sí ọmọ ọkọ rẹ̀ tí ó kú, kí orúkọ ọkọ rẹ̀ náà má baà parẹ́ ní Israẹli.

Diutaronomi 25

Diutaronomi 25:1-8