Diutaronomi 25:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn ìwọ̀n ati òṣùnwọ̀n rẹ gbọdọ̀ péye, kí ọjọ́ rẹ lè pẹ́ lórí ilẹ̀ tí OLUWA Ọlọrun rẹ fún ọ.

Diutaronomi 25

Diutaronomi 25:11-19