Diutaronomi 24:3 BIBELI MIMỌ (BM)

ṣugbọn tí kò tún wu ọkọ titun náà, tí òun náà tún já ìwé ìkọ̀sílẹ̀ fún un, tí ó sì tún tì í jáde kúrò ninu ilé rẹ̀, tabi tí ọkọ keji tí obinrin yìí fẹ́ bá kú,

Diutaronomi 24

Diutaronomi 24:1-5