Diutaronomi 24:16 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ẹ kò gbọdọ̀ pa baba dípò ọmọ rẹ̀, bẹ́ẹ̀ sì ni ẹ kò gbọdọ̀ pa ọmọ dípò baba, olukuluku ni yóo kú fún ẹ̀ṣẹ̀ tí ó bá dá.

Diutaronomi 24

Diutaronomi 24:9-21