Diutaronomi 24:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ gbọdọ̀ dá a pada fún un ní alẹ́, kí ó lè rí aṣọ fi bora sùn, kí ó lè súre fun yín. Èyí yóo jẹ́ ìwà òdodo lójú OLUWA Ọlọrun yín.

Diutaronomi 24

Diutaronomi 24:12-15