Diutaronomi 24:10 BIBELI MIMỌ (BM)

“Tí ẹ bá yá ẹnìkejì yín ní nǹkankan, ẹ kò gbọdọ̀ wọ ilé rẹ̀ lọ láti wá ohun tí yóo fi dógò.

Diutaronomi 24

Diutaronomi 24:5-18