Diutaronomi 23:9 BIBELI MIMỌ (BM)

“Nígbà tí ẹ bá jáde lọ láti bá àwọn ọ̀tá yín jagun, tí ẹ bá sì wà ninu àgọ́, ẹ níláti yẹra fún ohunkohun tíí ṣe ibi.

Diutaronomi 23

Diutaronomi 23:8-12