Diutaronomi 23:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn OLUWA Ọlọrun yín kò fetí sí ti Balaamu, ó yí èpè náà sí ìre fun yín nítorí pé ó fẹ́ràn yín.

Diutaronomi 23

Diutaronomi 23:1-8