Diutaronomi 23:17 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ẹnikẹ́ni ninu àwọn eniyan Israẹli, kì báà jẹ́ ọkunrin tabi obinrin, kò gbọdọ̀ sọ ara rẹ̀ di alágbèrè ní ilé oriṣa kankan.

Diutaronomi 23

Diutaronomi 23:7-21