Diutaronomi 22:15 BIBELI MIMỌ (BM)

“Kí baba ati ìyá ọmọbinrin yìí mú aṣọ ìbálé rẹ̀ jáde, kí wọ́n sì mú un tọ àwọn àgbààgbà ìlú náà lọ ní ẹnubodè.

Diutaronomi 22

Diutaronomi 22:8-24