Diutaronomi 22:1 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ẹ kò gbọdọ̀ máa wo mààlúù tabi aguntan arakunrin yín, kí ó máa ṣìnà lọ, kí ẹ sì mójú kúrò, ẹ níláti fà á tọ olówó rẹ̀ lọ.

Diutaronomi 22

Diutaronomi 22:1-7