Diutaronomi 21:20 BIBELI MIMỌ (BM)

kí wọ́n wí fún àwọn àgbààgbà ìlú náà pé, ‘Ọmọ wa yìí ya olóríkunkun ati aláìgbọràn, kì í gbọ́rọ̀ sí wa lẹ́nu. Oníjẹkújẹ ati onímukúmu sì ni.’

Diutaronomi 21

Diutaronomi 21:16-22