Diutaronomi 20:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí OLUWA Ọlọrun yín bá fi ìlú náà le yín lọ́wọ́, kí ẹ fi idà pa gbogbo àwọn ọkunrin tí wọ́n wà níbẹ̀.

Diutaronomi 20

Diutaronomi 20:3-16