Diutaronomi 20:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí wọ́n bá rán iṣẹ́ alaafia pada, tí wọ́n sì ṣí ìlẹ̀kùn wọn fun yín, kí ẹ kó gbogbo àwọn ará ìlú náà lẹ́rú kí wọ́n sì máa sìn yín.

Diutaronomi 20

Diutaronomi 20:1-20