Diutaronomi 2:33 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA Ọlọrun wa fi lé wa lọ́wọ́, a ṣẹgun rẹ̀, ati òun ati àwọn ọmọ rẹ̀, ati gbogbo àwọn eniyan rẹ̀.

Diutaronomi 2

Diutaronomi 2:23-37