Diutaronomi 2:27 BIBELI MIMỌ (BM)

‘Jẹ́ kí n kọjá láàrin ilẹ̀ rẹ. Ojú ọ̀nà tààrà ni n óo máa gbà lọ. N kò ní yà sí ọ̀tún tabi sí òsì.

Diutaronomi 2

Diutaronomi 2:26-34