Diutaronomi 2:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Láti òní lọ, n óo mú kí ẹ̀rù yín máa ba gbogbo àwọn eniyan tí wọ́n wà láyé yìí, tí wọ́n bá gbúròó yín, wọn yóo máa gbọ̀n, ojora yóo sì mú wọn nítorí yín.

Diutaronomi 2

Diutaronomi 2:21-33