Diutaronomi 2:20 BIBELI MIMỌ (BM)

(Ibẹ̀ ni wọ́n ń pè ní ilẹ̀ Refaimu, nítorí pé, àwọn Refaimu ni wọ́n ti ń gbé ibẹ̀ tẹ́lẹ̀, ṣugbọn àwọn ará Amoni a máa pè wọ́n ní Samsumimu.

Diutaronomi 2

Diutaronomi 2:17-30