Diutaronomi 2:10 BIBELI MIMỌ (BM)

(Ìran àwọn òmìrán kan tí à ń pè ní Emimu ní ń gbé ibẹ̀ tẹ́lẹ̀ rí. Wọ́n pọ̀, wọ́n sì lágbára. Wọ́n ṣígbọnlẹ̀ bí àwọn ọmọ Anaki.

Diutaronomi 2

Diutaronomi 2:3-14