Diutaronomi 19:8 BIBELI MIMỌ (BM)

“Bí OLUWA Ọlọrun yín bá sì mú kí ilẹ̀ yín tóbi síi gẹ́gẹ́ bí ó ti búra fún àwọn baba yín, tí ó bá fun yín ní gbogbo ilẹ̀ tí ó ṣèlérí fún àwọn baba yín,

Diutaronomi 19

Diutaronomi 19:1-16