Diutaronomi 19:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn yòókù yóo gbọ́, ẹ̀rù yóo bà wọ́n, wọn kò sì ní ṣe irú nǹkan burúkú bẹ́ẹ̀ mọ́ láàrin yín.

Diutaronomi 19

Diutaronomi 19:19-21