Diutaronomi 19:11 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ṣugbọn bí ẹnikẹ́ni bá kórìíra aládùúgbò rẹ̀, tí ó bá ba dè é, tí ó mọ̀ọ́nmọ̀ pa á, tí ó sì sálọ sí ọ̀kan ninu àwọn ìlú wọnyi,

Diutaronomi 19

Diutaronomi 19:8-13