Diutaronomi 18:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Kí ẹ fún àwọn alufaa ní àkọ́so oko yín, ati àkọ́pọn ọtí waini yín, ati àkọ́ṣe òróró yín, ati irun aguntan tí ẹ bá kọ́kọ́ rẹ́.

Diutaronomi 18

Diutaronomi 18:1-10