Diutaronomi 17:2 BIBELI MIMỌ (BM)

“Bí ọkunrin kan tabi obinrin kan láàrin àwọn ìlú tí OLUWA Ọlọrun yín fun yín bá ṣe ohun tí ó burú lójú OLUWA Ọlọrun yín, nípa pé ó da majẹmu rẹ̀,

Diutaronomi 17

Diutaronomi 17:1-11