Diutaronomi 16:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Olukuluku ọkunrin yóo mú ọrẹ wá gẹ́gẹ́ bí ó bá ti fẹ́ ati gẹ́gẹ́ bí OLUWA Ọlọrun yín bá ti bukun un.

Diutaronomi 16

Diutaronomi 16:15-21